Jeremiah 25:36 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ gbọ́ igbe àwọn olùṣọ́-aguntan ati ẹkún ẹ̀dùn ti àwọn oluwa agbo ẹran; nítorí OLUWA ń ba ibùjẹ ẹran wọn jẹ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ohùn ẹkun awọn oluṣọ-agutan, ati igbe awọn ọlọla agbo-ẹran li a o gbọ́: nitori Oluwa bà papa-oko tutu wọn jẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbọ́ igbe àwọn olùsọ́ àgùntàn, àti ìpohùnréré ẹkún àwọn olórí agbo ẹran; nítorí pé OLÚWA ń pa pápá oko tútù wọn run.