Jeremiah 25:38 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Bíi kinniun tí ó fi ihò rẹ̀ sílẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni OLUWA fi àwọn eniyan rẹ̀ sílẹ̀, ilẹ̀ wọn sì ti di ahoro nítorí idà apanirun ati ibinu gbígbóná OLUWA.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O ti fi pantiri rẹ̀ silẹ bi kiniun nitori ti ilẹ wọn di ahoro, niwaju ibinu idà aninilara, ati niwaju ibinu kikan rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gẹ́gẹ́ bí kìnnìún yóò fi ibùba rẹ̀ sílẹ̀, ilẹ̀ wọn yóò sì di ahoro, nítorí idà àwọn anínilára, àti nítorí ìbínú ńlá OLÚWA.