Jeremiah 25:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó ní, “Nítorí pé ẹ kò gbọ́ràn sí mi lẹ́nu,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina, bayi li Oluwa awọn ọmọ-ogun wi: nitori ti ẹnyin kò gbọ́ ọ̀rọ mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà, Ọlọ́run alágbára sọ èyí: “Nítorí wí pé ẹ̀yin kò fetí sí ọ̀rọ̀ mi,