Jeremiah 26:12 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Jeremaya bá sọ fún àwọn ìjòyè ati gbogbo àwọn eniyan pé, “OLUWA ni ó rán mi láti sọ àsọtẹ́lẹ̀ tí ẹ gbọ́ sí ilé yìí ati ìlú yìí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni Jeremiah wi fun awọn ijoye ati gbogbo enia pe, Oluwa rán mi lati sọ asọtẹlẹ gbogbo ọ̀rọ ti ẹnyin gbọ́, si ile yi ati si ilu yi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni Jeremáyà sọ fún gbogbo àwọn aláṣẹ àti gbogbo àwọn ènìyàn wí pé: “OLÚWA rán mi láti sọ àsọtẹ́lẹ̀ ní ilé yìí àti ìlú yìí, gbogbo ohun tí ẹ ti gbọ́.