Jeremiah 31:11 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí OLUWA yóo ra ilé Jakọbu pada, yóo rà wọ́n pada lọ́wọ́ ẹni tí ó lágbára jù wọ́n lọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori Oluwa ti tú Jakobu silẹ, o si rà a pada li ọwọ awọn ti o li agbara jù u lọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí OLÚWA ti tú Jákọ́bù sílẹ̀, o sì ràá padà ní ọwọ́ àwọn tí ó lágbára jù ú lọ