Jeremiah 31:17 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ìrètí ń bẹ fún ọ lẹ́yìn ọ̀la, àwọn ọmọ rẹ yóo pada sí orílẹ̀-èdè wọn. Èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ireti si wà ni igbẹhin rẹ, li Oluwa wi, pe awọn ọmọ rẹ yio pada si agbegbe wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí ìrètí wà fún ọjọ́ iwájú rẹ,” ni OLÚWA wí. “Àwọn ọmọ rẹ yóò padà wá sí ilẹ̀ wọn.