Jeremiah 31:29 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Tó bá dìgbà náà, àwọn eniyan kò ní máa wí mọ́ pé, ‘Àwọn baba ni wọ́n jẹ èso àjàrà kíkan, àwọn ọmọ wọn ni eyín kan.’
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Li ọjọ wọnni, nwọn kì yio wi mọ pe, Awọn baba ti jẹ eso ajara aipọn, ehín si ti kan awọn ọmọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ní ọjọ́ wọ̀n-ọn-nì àwọn ènìyàn kò ní sọ mọ́ pé: “ ‘Àwọn baba ti jẹ èṣo kíkan àti pé ẹyín kan àwọn ọmọdé.’