Jeremiah 31:37 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àfi bí eniyan bá lè wọn ojú ọ̀run, tí ó sì lè wádìí ìpìlẹ̀ ayé, ni òun lè ké àwọn ọmọ Israẹli kúrò, nítorí gbogbo ohun tí wọ́n ṣe.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bayi li Oluwa wi, Bi a ba le wọ̀n ọrun loke, ti a si le wá ipilẹ aiye ri nisalẹ, emi pẹlu yio ta iru-ọmọ Israeli nù nitori gbogbo eyiti nwọn ti ṣe, li Oluwa wi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èyí ni ohun tí OLÚWA wí: “Àyàfi tí a bá lé àwọn ọ̀run lókè tí ìpìlẹ̀ ayé sì di àwárí ní ìṣàlẹ̀, ni èmi yóò kọ àwọn Ísírẹ́lì nítorí ohun gbogbo tí wọ́n ti ṣe,” ni OLÚWA wí.