Jeremiah 31:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí pé ọjọ́ kan ń bọ̀, tí àwọn aṣọ́nà yóo pè yín láti orí òkè Efuraimu pé, ‘Ẹ dìde, ẹ jẹ́ kí á lọ sí òkè Sioni, sí ọ̀dọ̀ OLUWA Ọlọrun wa.’ ”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori ọjọ na ni eyi, ti awọn oluṣọ lori oke Efraimu yio kigbe pe, Ẹ dide, ẹ si jẹ ki a goke lọ si Sioni sọdọ Oluwa, Ọlọrun wa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọjọ́ kan máa wà tí àwọn olùṣọ́ yóò kígbe jáde lórí òkè Éfráímù wí pé, ‘Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí a gòkè lọ sí Síónì, ní ọ̀dọ̀ OLÚWA Ọlọ́run wa.’ ”