Jeremiah 32:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọmọ ogun Babiloni dó ti Jerusalẹmu ní àkókò yìí, Jeremaya wolii sì wà ní ẹ̀wọ̀n tí wọ́n sọ ọ́ sí, ní àgbàlá ààfin ọba Juda.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni ogun ọba Babeli ha Jerusalemu mọ: a si se Jeremiah woli mọ agbala ile túbu, ti o wà ni ile ọba Juda.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ogun Ọba Bábílónì ìgbà náà há Jérúsálẹ́mù mọ́. A sì ṣé wòlíì Jeremáyà mọ́ inú túbú tí wọ́n ń sọ́ ní àgbàlá ilé Ọba Júdà.