Jeremiah 32:20 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
ìwọ tí o ṣe iṣẹ́ abàmì, ati iṣẹ́ ìyanu ní ilẹ̀ Ijipti, o sì tún ń ṣe iṣẹ́ náà títí di òní ní Israẹli ati láàrin gbogbo eniyan; o sì ti fìdí orúkọ rẹ múlẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ó ti rí lónìí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹniti o gbe àmi ati iṣẹ-iyanu kalẹ ni Egipti, titi di oni yi, ati lara Israeli, ati lara enia miran: ti iwọ si ti ṣe orukọ fun ara rẹ, gẹgẹ bi o ti ri li oni yi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
O ṣe iṣẹ́ àmì àti iṣẹ́ ìyanu ńlá ní Éjíbítì. O sì ń ṣe é títí di òní ní Ísírẹ́lì àti lára ọmọ ènìyàn tí ó sì ti gba òkìkí tí ó jẹ́ tìrẹ.