Jeremiah 33:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tó bá yá, tí àkókò bá tó, n óo mú kí ẹ̀ka òdodo kan ó sọ jáde ní ilé Dafidi, yóo máa ṣe ìdájọ́ ẹ̀tọ́ ati ti òdodo ní ilẹ̀ náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Li ọjọ wọnni, ati li akoko na, emi o jẹ ki Ẹka ododo ki o hu soke fun Dafidi; ẹniti yio si ṣe idajọ ati ododo ni ilẹ na.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“ ‘Ní ọjọ́ wọ̀n ọn nì àti ní àkókò náà, Èmi ó gbé olódodo dìde láti ẹ̀ka Dáfídì. Yóò ṣe ìdájọ́ àti ohun tí ó tọ́ ní ilẹ̀ náà.