Jeremiah 35:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Lọ sí ilé àwọn ọmọ Rekabu kí o bá wọn sọ̀rọ̀, mú wọn wá sinu ọ̀kan ninu àwọn yàrá tí ó wà ninu ilé OLUWA, kí o sì fi ọtí lọ̀ wọ́n.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Lọ si ile awọn ọmọ Rekabu, ki o si ba wọn sọ̀rọ, ki o si mu wọn wá si ile Oluwa, si ọkan ninu iyara wọnni, ki o si fun wọn li ọti-waini mu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Lọ sí ilé àwọn ọmọ Rékábù, kí o sì bá wọn sọ̀rọ̀, kí o sì mú wọn wá sí ilé OLÚWA, sí ọ̀kan nínú iyàrá wọ̀n-ọn-nì, kí o sì fún wọn ní ọtí wáìnì mu.”