Jeremiah 35:4 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
mo mú wọn wá sinu ilé OLUWA. Mo kó wọn lọ sinu yàrá àwọn ọmọ-ẹ̀yìn Hanani, ọmọ Igidalaya eniyan Ọlọrun, yàrá náà wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ yàrá àwọn ìjòyè, lókè yàrá Maaseaya ọmọ Ṣalumu, aṣọ́nà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Mo si mu wọn wá si ile Oluwa, sinu iyara awọn ọmọ Hanani, ọmọ Igdaliah, enia Ọlọrun, ti o wà lẹba iyara awọn ijoye, ti o wà li oke iyara Maaseiah, ọmọ Ṣallumu, olutọju ẹnu-ọ̀na,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Mo sì mú wọn wá sí ilé OLÚWA sínú iyàrá Hanani ọmọ Ígídálíà, ènìyàn Ọlọ́run, tí ó wà lẹ́bàá yàrá àwọn ìjòyè, tí ó wà ní òkè yàrá Mááséíà, ọmọ Sálúmù, olùtọ́jú ẹnu-ọ̀nà,