Jeremiah 36:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n ní kí ó jókòó, kí ó kà á fún àwọn, Baruku bá kà á fún wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn si wi fun u pe, Joko nisisiyi, ki o si kà a li eti wa. Baruku si kà a li eti wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n sì wí fún pé, “Jòkòó, jọ̀wọ́ kà á sí etí wa!” Nígbà náà ni Bárúkì sì kàá ní etí wọn.