Jeremiah 37:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣugbọn Sedekaya ati àwọn ẹmẹ̀wà rẹ̀ ati àwọn eniyan náà kò pa ọ̀rọ̀ tí OLUWA ní kí Jeremaya wolii sọ fún wọn mọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn ati on, ati awọn iranṣẹ rẹ̀, ati awọn enia ilẹ na, kò fetisi ọ̀rọ Oluwa, ti o sọ nipa Jeremiah, woli.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n àti òun àti àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ àti àwọn ènìyàn ilẹ̀ náà kò fetísí ọ̀rọ̀ OLÚWA tí ó sọ nípa wòlíì Jeremáyà.