Jeremiah 37:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
OLUWA sọ fún Jeremaya wolii pé kí ó sọ fún àwọn tí ọba Juda rán láti wá wádìí ọ̀rọ̀ lọ́wọ́ rẹ̀ pé,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni ọ̀rọ Oluwa tọ̀ Jeremiah, woli wá, wipe,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni ọ̀rọ̀ Ọlọ́run tọ Jeremáyà òjíṣẹ́ Ọlọ́run wá: