Jeremiah 38:1 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí Ṣefataya, ọmọ Matani, ati Gedalaya, ọmọ Paṣuri, ati Jukali, ọmọ Ṣelemaya, ati Paṣuri ọmọ Malikaya gbọ́ ọ̀rọ̀ tí Jeremaya ń sọ fún gbogbo àwọn eniyan pé,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
NIGBANA ni Ṣefatiah, ọmọ Mattani, ati Gedaliah, ọmọ Paṣuri, ati Jukali, ọmọ Ṣelemiah, ati Paṣuri ọmọ Malkiah, gbọ́ gbogbo ọ̀rọ ti Jeremiah ti sọ fun gbogbo enia, wipe,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Sefatíà ọmọ Mátanì, Gédáyà ọmọ Páṣúrì, Jéhúdù ọmọ Selemáyà àti Páṣúrì ọmọ Málíkíà gbọ́ ohun tí Jeremáyà ń sọ fún àwọn ènìyàn nígbà tí ó sọ wí pé,