Jeremiah 38:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ebedimeleki bá mú àwọn ọkunrin mẹta náà, wọ́n lọ sí yàrá kan ní ilé ìṣúra tí ó wà láàfin ọba. Ó mú àwọn àkísà ati àwọn aṣọ tí wọ́n ti gbó níbẹ̀, ó so okùn mọ́ wọn, ó sì nà án sí Jeremaya ninu kànga.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ebedmeleki si mu awọn enia na pẹlu rẹ̀, o si lọ si ile ọba labẹ iyara iṣura, o si mu akisa ati oṣuka lati ibẹ wá, o si fi okùn sọ̀ wọn kalẹ si Jeremiah ninu iho.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ebedimélékì kó àwọn ọkùnrin náà pẹ̀lú rẹ̀, wọ́n lọ sínú yàrá kan nínú ààfin Ọba. Ó mú àwọn aṣọ àkísà àti okùn tọ Jeremáyà lọ nínú àmù.