Jeremiah 38:12 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ó bá sọ fún Jeremaya pé kí ó fi àwọn àkísà ati àwọn aṣọ tí wọ́n ti gbó náà sí abíyá mejeeji, kí ó fi okùn kọ́ ara rẹ̀ lábíyá. Jeremaya sì ṣe bẹ́ẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ebedmeleki, ara Etiopia, si sọ fun Jeremiah pe, Fi akisa ati oṣuka wọnyi si abẹ abia rẹ, lori okùn. Jeremiah si ṣe bẹ̃.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ebedimélékì sọ fún Jeremáyà pé, “Fi àkísà àti okùn bọ abẹ́ abíyá rẹ, Jeremáyà sì ṣe bẹ́ẹ̀.”