Jeremiah 38:13 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Wọ́n bá fi okùn fa Jeremaya jáde kúrò ninu kànga. Jeremaya bá ń gbé gbọ̀ngàn àwọn tí wọn ń ṣọ́ ààfin.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bẹ̃ni nwọn fi okùn fà Jeremiah soke, nwọn si mu u goke lati inu iho wá: Jeremiah si wà ni agbala ile-tubu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Báyìí ni wọ́n ṣe yọ ọ́ jáde, ó sì ń gbé àgbàlá àwọn ẹ̀ṣọ́.