Jeremiah 38:23 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
“Gbogbo àwọn aya rẹ ati àwọn ọmọ rẹ ni wọn yóo kó lọ sọ́dọ̀ àwọn ará Kalidea, ìwọ gan-an kò sì ní bọ́ lọ́wọ́ wọn. Ọwọ́ ọba Babiloni yóo tẹ̀ ọ́, wọn yóo sì dáná sun ìlú yìí.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn o si mu gbogbo awọn aya rẹ ati awọn ọmọ rẹ jade tọ awọn ara Kaldea lọ: iwọ kì yio si sala kuro li ọwọ wọn, ọwọ ọba Babeli yio si mu ọ: iwọ o si mu ki nwọn ki o fi iná kun ilu yi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Wọn yóò kó àwọn ìyàwó àti ọmọ rẹ wá sí Bábílónì. Ìwọ gan-an kò ní bọ́ níbẹ̀, Ọba Bábílónì yóò mú ọ, wọn yóò sì jó ìlú yìí kanlẹ̀.”