Jeremiah 38:24 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Sedekaya ọba bá kìlọ̀ fún Jeremaya pé, “Má jẹ́ kí ẹnikẹ́ni mọ gbogbo nǹkan tí a jọ sọ, o kò sì ní kú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Sedekiah si wi fun Jeremiah pe, Máṣe jẹ ki ẹnikan mọ̀ niti ọ̀rọ wọnyi, ki iwọ má ba kú.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni Sedekáyà sọ fún Jeremáyà pé, “Má ṣe jẹ́ kí ẹnikẹ́ni mọ̀ nípa ọ̀rọ̀ yìí, tàbí kí o kú.