Jeremiah 38:25 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Bí àwọn ìjòyè bá gbọ́ pé a jọ sọ̀rọ̀, bí wọn bá wá sọ́dọ̀ rẹ tí wọn ní kí o sọ nǹkan tí o bá mi sọ fún àwọn, ati èsì tí mo fún ọ, tí wọn bẹ̀ ọ́ pé kí o má fi ohunkohun pamọ́ fún àwọn, tí wọn sì ṣe ìlérí pé àwọn kò ní pa ọ́,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn bi awọn ijoye ba gbọ́ pe emi ti ba ọ sọ̀rọ, bi nwọn ba si wá sọdọ rẹ, ti nwọn sọ fun ọ pe, Sọ fun wa nisisiyi eyi ti iwọ ti sọ fun ọba, máṣe fi pamọ fun wa, awa kì o si pa ọ; ati eyi ti ọba sọ fun ọ pẹlu:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Tí àwọn ìjòyè bá mọ̀ pé mo bá ọ sọ̀rọ̀, tí wọ́n bá wá bá ọ wí pé, ‘Sọ fún wa ohun tí o bá Ọba sọ tàbí ohun tí Ọba sọ fún ọ; má ṣe fi pamọ́ fún wa tàbí kí a pa ọ́,’