Jeremiah 38:26 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
sọ fún wọn pé ẹ̀bẹ̀ ni ò ń bẹ̀ mí pé kí n má dá ọ pada sí ilé Jonatani; kí o má baà kú sibẹ.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni ki iwọ ki o wi fun wọn pe, Emi mu ẹ̀bẹ mi wá siwaju ọba, pe ki o má mu mi pada lọ si ile Jonatani, lati kú sibẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
nígbà náà kí o sọ fún wọn, ‘Mò ń bẹ Ọba láti má jẹ́ kí n padà lọ sí ilé Jónátanì láti lọ kú síbẹ̀.’ ”