Jeremiah 38:28 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Jeremaya bá ń gbé gbọ̀ngàn àwọn tí wọn ń ṣọ́ ààfin títí di ọjọ́ tí ogun kó Jerusalẹmu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Jeremiah si ngbe agbala ile-túbu titi di ọjọ ti a kó Jerusalemu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jeremáyà wà nínú àgbàlá àwọn ẹ̀ṣọ́ títí di ọjọ́ tí wọ́n fi kó Jérúsálẹ́mù