Jeremiah 38:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ati pé dájúdájú, ìlú yìí yóo bọ́ sọ́wọ́ àwọn ọmọ ogun Babiloni, wọn yóo sì gbà á.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bayi li Oluwa wi pe, lõtọ a o fi ilu yi le ọwọ ogun ọba Babeli, ẹniti yio si kó o.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àti pé èyí ni ohun tí OLÚWA wí: ‘Ìdánilójú wà wí pé a ó fi ìlú náà lé ọwọ́ àwọn ọmọ ogun Bábílónì; tí yóò sì kó wa nígbékùn.’ ”