Jeremiah 38:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Sedekaya ọba bá dá wọn lóhùn, pé, “Ìkáwọ́ yín ló wà, n kò jẹ́ ṣe ohunkohun tí ó bá lòdì sí ìfẹ́ yín.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Sedekiah ọba, si wipe, Wò o, on wà li ọwọ nyin, nitori ọba kò le iṣe ohun kan lẹhin nyin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Sedekáyà Ọba sì wí pé, “Ó wà lọ́wọ́ yín. Ọba kò lè ṣe ohunkóhunm láti ta kò yín.”