Jeremiah 38:7 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà tí Ebedimeleki ará Etiopia tí ó jẹ́ ìwẹ̀fà ní ààfin ọba gbọ́ pé wọ́n ti ju Jeremaya sinu kànga. Ọba wà níbi tí ó jókòó sí ní ibodè Bẹnjamini.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati Ebedmeleki, ara Etiopia, iwẹfa kan, ti o wà ni ile ọba, gbọ́ pe, nwọn fi Jeremiah sinu iho: ọba joko nigbana li ẹnu-bode Benjamini;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n, Ebedimélékì, ará Kúṣì ìjòyè nínú ààfin Ọba gbọ́ pé wọ́n ti ju Jeremáyà sínú àmù. Nígbà tí Ọba jókòó lẹ́nubodè Bẹ́ńjámínì.