Jeremiah 39:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
OLUWA sọ fún Jeremaya nígbà tí ó wà ní àtìmọ́lé ní gbọ̀ngàn àwọn tí wọn ń ṣọ́ ààfin ọba, pé,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọrọ Oluwa si tọ̀ Jeremiah wá, nigbati a se e mọ ninu àgbala ile-túbu, wipe,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí Jeremáyà wà nínú túbú, ọ̀rọ̀ OLÚWA tọ̀ ọ́ wá wí pé: