Jeremiah 39:17 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
N óo gbà ọ́ sílẹ̀ ní ọjọ́ náà, wọn kò ní fà ọ́ lé àwọn tí ò ń bẹ̀rù lọ́wọ́. Èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn emi o gbà ọ li ọjọ na, li Oluwa wi: a kì o si fi ọ le ọwọ awọn enia na ti iwọ bẹ̀ru.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n Èmi yóò gbà ọ́ lọ́jọ́ náà ni OLÚWA wí. A kò ní fi ọ́ lé ọwọ́ àwọn tí o bẹ̀rù.