Jeremiah 4:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ kìlọ̀ fún àwọn orílẹ̀-èdè pé ó ń bọ̀, kéde fún Jerusalẹmu pé, àwọn ológun tí ń dó ti ìlú ń bọ̀, láti ilẹ̀ òkèèrè. Wọ́n ń kọ lálá sí àwọn ìlú Juda.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹ wi fun awọn orilẹ-ède; sa wò o, kede si Jerusalemu, pe, awọn ọluṣọ-ogun ti ilẹ jijin wá, nwọn si sọ ohùn wọn jade si ilu Juda.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Sọ èyí fún àwọn orílẹ̀ èdè, kéde rẹ̀ fún Jérúsálẹ́mù pé: ‘Ọmọ ogun ọ̀tá ń bọ̀ láti ilẹ̀ jínjìn wá Wọ́n sì ń kígbe ogun láti dojú kọ ìlú Júdà.