Jeremiah 4:17 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n yí i ká bí àwọn tí ó ń ṣọ́ oko, nítorí pé ó ti ṣọ̀tẹ̀ sí OLUWA. OLUWA ló sọ bẹ́ẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bi awọn ti nṣọ oko, bẹ̃ni nwọn wà yi i kakiri: nitori o ti ṣọtẹ̀ si mi, li Oluwa wi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n yí i ká bí ìgbà tí àwọn ọkùnrin bá ń ṣọ́ pápá, nítorí pé ó ti dìtẹ̀ sí mi,’ ” ni OLÚWA wí.