Jeremiah 4:20 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àjálù ń ṣubú lu àjálù, gbogbo ilẹ̀ ti parun. Lójijì àgọ́ mi wó lulẹ̀, aṣọ títa mi sì fàya ní ìṣẹ́jú kan.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iparun lori iparun ni a nke; nitori gbogbo ilẹ li o ti parun, lojiji ni agọ mi di ijẹ, pẹlu aṣọ ikele mi ni iṣẹju kan.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìparun ń gorí ìparun; Gbogbo ilẹ̀ náà sì ṣubú sínú ìparun Lọ́gán a wó àwọn àgọ́ mi, tí ó jẹ́ ohun ààbò mi níṣẹ́jú kan.