Jeremiah 4:24 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Mo wo àwọn òkè ńlá, wọ́n ń mì tìtì, gbogbo òkè kéékèèké ń sún lọ síhìn-ín sọ́hùn-ún.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Mo bojuwo gbogbo oke nla, sa wò o, o warìri ati gbogbo oke kekere mì jẹjẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Mo wo àwọn òkè ńlá, wọ́n wárìrì; gbogbo òkè kékèké mì jẹ̀jẹ̀.