Jeremiah 4:26 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Mo wò yíká, mo rí i pé gbogbo ilẹ̀ ọlọ́ràá ti di aṣálẹ̀, gbogbo ìlú sì ti di òkítì àlàpà níwájú OLUWA, nítorí ibinu ńlá rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Mo bojuwo, sa wò o, Karmeli di aginju, ati gbogbo ilu rẹ̀ li o wó lulẹ, niwaju Oluwa ati niwaju ibinu rẹ̀ gbigbona.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Mo bojú wò, ilẹ̀ eléṣo, ó sì di aṣálẹ̀ gbogbo àwọn ìlú inú rẹ̀ sì ṣubú sínú ìparun níwájú OLÚWA àti níwájú ríru ìbínú rẹ̀.