Jeremiah 4:27 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí OLUWA ti sọ pé, gbogbo ilẹ̀ náà yóo di ahoro; sibẹ òpin kò ní tíì dé.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori bayi li Oluwa wi pe: Gbogbo ilẹ ni yio di ahoro; ṣugbọn emi kì yio ṣe ipari tan.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èyí ni ohun tí OLÚWA wí “Gbogbo ìlú náà yóò sì di ahoro, síbẹ̀ èmi kì yóò pa á run pátapáta.