Jeremiah 4:28 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí èyí, ilẹ̀ yóo ṣọ̀fọ̀, ojú ọ̀run yóo sì ṣókùnkùn. Nítorí pé ó ti sọ bẹ́ẹ̀, ó ti rò ó dáradára, kò tíì jáwọ́ ninu rẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni kò ní yipada.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori eyi ni ilẹ yio ṣe kãnu, ati ọrun loke yio di dudu: nitori emi ti wi i, mo ti pete rẹ̀, emi kì o yi ọkàn da, bẹ̃ni kì o yipada kuro ninu rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà, ayé yóò pohùnréré ẹkún àwọn ọ̀run lókè yóò ṣóòkùn nítorí mo ti sọ, mo sì ti pète rẹ̀ mo ti pinnu, n kì yóò sì yí i padà.”