Jeremiah 4:6 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹ gbé àsíá sókè sí Sioni, pé kí wọn sá àsálà, kí wọn má ṣe dúró, nítorí mò ń mú ibi ati ìparun ńlá bọ̀ láti ìhà àríwá.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹ gbé ọpagun soke siha Sioni; ẹ kuro, ẹ má duro: nitori emi o mu buburu lati ariwa wá pẹlu ibajẹ nlanla.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Fi àmì láti sálọ sí Síónì hàn, sálọ fún ààbò láìsí ìdádúró. Nítorí èmi ó mú àjálù láti àríwá wá, àní ìparun tí ó burú jọjọ.”