Jeremiah 40:16 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn Gedalaya sọ fún Johanani, ọmọ Karea pé, “Má ṣe bẹ́ẹ̀, irọ́ ni ò ń pamọ́ Iṣimaeli.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn Gedaliah, ọmọ Ahikamu, sọ fun Johanani, ọmọ Karea pe, Iwọ kò gbọdọ ṣe nkan yi, nitori eke ni iwọ ṣe mọ Iṣmaeli.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n Jedáláyà ọmọ Áhíkámù sọ fún Jóhánánì ọmọ Káréà pé, “Má ṣe ṣe nǹkan yìí! Nítorí nǹkan tí ò ń sọ nípa Íṣímáẹ́lì kì í ṣe òtítọ́.”