Jeremiah 41:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà tí Johanani, ọmọ Karea ati gbogbo àwọn olórí ogun tí wọ́n wà pẹlu rẹ̀ gbọ́ gbogbo iṣẹ́ ibi tí Iṣimaeli, ọmọ Netanaya ṣe,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn nigbati Johanani, ọmọ Karea, ati gbogbo awọn olori ogun ti o pẹlu rẹ̀, gbọ́ ibi ti Iṣmaeli, ọmọ Netaniah ti ṣe,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí Johánánì ọmọkùnrin Kárè àti gbogbo àwọn olórí ogun tí wọ́n wà pẹ̀lú rẹ̀ gbọ́ nípa gbogbo ìpànìyàn náà tí Ísímáẹ́lì ọmọ Nétanáyà ti ṣe.