Jeremiah 41:12 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
wọ́n kó gbogbo àwọn ọmọ ogun wọn lọ gbógun ti Iṣimaeli, wọ́n bá a létí odò ńlá tí ó wà ní Gibeoni.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni nwọn kó gbogbo awọn ọkunrin, nwọn si lọ iba Iṣmaeli, ọmọ Netaniah jà, nwọn si ri i li ẹba omi nla ti o wà ni Gibeoni.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n kó gbogbo àwọn ọkùnrin wọn, wọ́n sì, lọ bá Ísímáẹ́lì ọmọ Nétanáyà jà. Wọ́n pàdé rẹ̀ ní odò kan lẹ́bàá Gídéónì.