Jeremiah 41:13 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí gbogbo àwọn eniyan tí wọ́n wà lọ́dọ̀ Iṣimaeli rí Johanani, ọmọ Karea ati gbogbo àwọn olórí ogun tí wọ́n wà pẹlu rẹ̀, inú wọn dùn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si ṣe, nigbati gbogbo awọn enia ti o wà pẹlu Iṣmaeli ri Johanani, ọmọ Karea, ati gbogbo awọn olori ogun ti o pẹlu rẹ̀, nwọn si yọ̀,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí gbogbo àwọn ènìyàn Ísímáẹ́lì tí wọ́n wà pẹ̀lú rẹ̀ rí Jóhánánì ọmọkùnrin Káréà àti àwọn ọmọ-ogun rẹ̀ pẹ̀lú rẹ̀, wọ́n sì yọ̀.