Jeremiah 41:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣugbọn Iṣimaeli, ọmọ Netanaya, pẹlu àwọn mẹjọ sá àsálà lọ sí ilẹ̀ àwọn ará Amoni.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn Iṣmaeli, ọmọ Netaniah, bọ́ lọwọ Johanani pẹlu ọkunrin mẹjọ, o si lọ sọdọ awọn ọmọ Ammoni.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n Ísímáẹ́lì ọmọkùnrin Nétanáyà àti àwọn mẹ́jọ nínú àwọn ọkùnrin rẹ̀ bọ́ lọ́wọ́ Jóhánánì, wọ́n sì sálọ sí Ámónì.