Jeremiah 41:17 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Wọ́n lọ ń gbé Geruti Kimhamu, tí ó wà lẹ́bàá Bẹtilẹhẹmu. Wọ́n pinnu láti kó lọ sí ilẹ̀ Ijipti nítorí ẹ̀rù àwọn ará Kalidea ń bà wọ́n;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn si kuro nibẹ, nwọn si joko ni ibugbe Kinhamu, ti o wà lẹba Betlehemu, lati lọ ide Egipti.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n sì dúró ní Gérútì Kímámù ní ẹ̀bá Bẹ́tílẹ́hẹ́mù nínú ìrìnàjò wọn sí Éjíbítì.