Jeremiah 41:18 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
nítorí pé Iṣimaeli ọmọ Netanaya ti pa Gedalaya, ọmọ Ahikamu, tí ọba Babiloni fi ṣe gomina ilẹ̀ náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitoriti ẹ̀ru ba wọn niwaju awọn ara Kaldea, nitoriti Iṣmaeli ọmọ Netaniah, ti pa Gedaliah, ọmọ Ahikamu ẹniti ọba Babeli fi jẹ bãlẹ ni ilẹ na.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Láti gba àwọn Bábílónì sílẹ̀. Wọ́n bẹ̀rù wọn nítorí wí pé, “Ísímáẹ́lì ọmọ Nétanáyà ti pa Jedaláyà ọmọ Álíkámù èyí tí Ọba Bábílónì ti yàn gẹ́gẹ́ bí i gómínà lórí ilẹ̀ náà.”