Jeremiah 43:1 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà tí Jeremaya parí gbogbo ọ̀rọ̀ tí OLUWA Ọlọrun wọn rán an sí gbogbo àwọn ará ìlú,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si ṣe, nigbati Jeremiah pari ọ̀rọ isọ fun gbogbo awọn enia, ani gbogbo ọ̀rọ Oluwa Ọlọrun wọn, eyiti Oluwa Ọlọrun wọn ti rán a si wọn, ani gbogbo ọ̀rọ wọnyi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí Jeremáyà párí sísọ ọ̀rọ̀ tí OLÚWA Ọlọ́run rán an sí wọn tan.