Jeremiah 43:12 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Yóo dáná sun àwọn ilé àwọn oriṣa ilẹ̀ Ijipti; yóo jó wọn níná; yóo sì kó àwọn ará ìlú lọ sí ìgbèkùn; yóo fọ ilẹ̀ Ijipti mọ́ bí darandaran tíí ṣa eégbọn kúrò lára aṣọ rẹ̀, yóo sì jáde kúrò níbẹ̀ ní alaafia.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi o si dá iná kan ni ile awọn oriṣa Egipti; on o si sun wọn, yio si kó wọn lọ; on o si fi ilẹ Egipti wọ ara rẹ̀ laṣọ gẹgẹ bi oluṣọ-agutan ti iwọ̀ aṣọ rẹ̀; yio si jade lati ibẹ lọ li alafia.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Yóò dá, iná sun Tẹ́ḿpìlì àwọn òrìṣà Éjíbítì, yóò sun Tẹ́ḿpìlì àwọn òrìṣà Éjíbítì, yóò sì mú wọn lọ ìgbèkùn. Gẹ́gẹ́ bí olùṣọ́ àgùntàn, yóò ró aṣọ rẹ̀ mọ́ra, bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ ni yóò ró Éjíbítì òun yóò sì lọ kúrò níbẹ̀ ní àlàáfíà