Jeremiah 44:11 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Nítorí náà, OLUWA àwọn ọmọ ogun, Ọlọrun Israẹli ní, ‘Ẹ wò ó, n óo dójúlé yín, n óo sì pa gbogbo ọmọ Juda run.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina bayi li Oluwa awọn ọmọ-ogun, Ọlọrun Israeli, wi pe, wò o emi doju mi kọ nyin fun ibi, ati lati ke gbogbo Juda kuro.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Fún ìdí èyí, báyìí ni OLÚWA Ọlọ́run àwọn Ísírẹ́lì wí: Mo ti pinnu láti mú ibi wá sí orí yín àti láti pa Júdà run.