Jeremiah 44:20 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Jeremaya sọ fún gbogbo àwọn eniyan tí wọ́n dá a lóhùn, lọkunrin ati lobinrin pé:
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni Jeremiah sọ fun gbogbo awọn enia, fun awọn ọkunrin, ati fun awọn obinrin, ati fun gbogbo awọn enia ti o ti fun u li èsi yi wipe.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wàyí o, Jeremáyà sọ fún àwọn ọ̀pọ̀ ènìyàn náà, ọkùnrin àti obìnrin, tí wọn sì ń dáhùn pé,